Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 5:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Námánì jẹ́ olórí ogun ọba Árámù. Ó jẹ́ ènìyàn ńlá níwájú ọ̀gá rẹ̀, wọ́n sì bu ọlá fún un, nítorí nípasẹ̀ rẹ̀ Olúwa fún wa ní ìṣẹ́gun fún Árámù. Ó jẹ́ alágbára, akọni ọkùnrin ṣùgbọ́n, ó dẹ́tẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 5

Wo 2 Ọba 5:1 ni o tọ