Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsìnyìí ẹgbẹgbẹ́ láti Árámù ti jáde lọ láti mú ọmọ obìnrin kékeré kan ní ìgbèkùn láti Ísírẹ́lì, ó sì sin ìyàwó Námánì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 5

Wo 2 Ọba 5:2 ni o tọ