Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 24:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéhóíákímù ọba Júdà àti ìyá rẹ̀ àti àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, àti àwọn ìwẹ̀fà àti àwọn ìjòyè gbogbo wọn sì jọ̀wọ́ ara wọn fún un.Ní ọdún kẹjọ ìjọba rẹ̀ ti ọba Bábílónì ó mú Jéhóíákínì ẹlẹ́wọ̀n.

Ka pipe ipin 2 Ọba 24

Wo 2 Ọba 24:12 ni o tọ