Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 23:35 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéhóíákímù sì san fún Fáráò Nékónì fàdákà àti wúrà tí ó béèrè. Lati ṣe bẹ́ẹ̀, ó bu owó òde fún ilẹ̀ náà láti san, ó fi agbára gba fàdákà àti wúrà láti ọwọ́ àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà ní ìbámu pẹ̀lú iye tí a pín.

Ka pipe ipin 2 Ọba 23

Wo 2 Ọba 23:35 ni o tọ