Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 23:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Fáráò Nékò ṣe Élíákímù ọmọ Jòṣíàh ní ọba ní ipò baba rẹ̀ Jòsáyà. Ó sì yí orúkọ Élíákímù padà sí Jéhóíákímù. Ṣùgbọ́n ó mú Jéhóáhásì, ó sì gbéé lọ sí Éjíbítì, níbẹ̀ ni ó sì kú.

Ka pipe ipin 2 Ọba 23

Wo 2 Ọba 23:34 ni o tọ