Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 22:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì ṣe èyí tí ó dára lójú Olúwa, ó sì rìn ní ọ̀nà Dáfídì bàbá a rẹ̀, kò sì yípadà sí apá ọ̀tún tàbí sí apá òsì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 22

Wo 2 Ọba 22:2 ni o tọ