Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 22:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jòsáyà jẹ́ ọmọ ọdún mẹ́jọ nígbà tí ó di ọba, ó sì jọba ní Jérúsálẹ́mù fún ọdún mọ́kànlélọ́gbọ̀n. Orúkọ ìyá rẹ̀ a máa jẹ́ Jédídà ọmọbìnrin Ádáyà; ó wá láti Bósíkátì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 22

Wo 2 Ọba 22:1 ni o tọ