Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 22:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Hílíkíyà àlùfáà, Áhíkámù àti Ákíbórì pẹ̀lú Ṣáfánì, lọ sí ọ̀dọ̀ wòlíì obìnrin Húlídà láti lọ bá a sọ̀rọ̀ tí ó jẹ́ aya Ṣálúmù ọmọ Tíkífà ọmọ Háríhásì alábojútó ibi ìpa aṣọ mọ́ sí. Ó ń gbé ní Jérúsálẹ́mù ní ìdà kejì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 22

Wo 2 Ọba 22:14 ni o tọ