Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 22:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lọ, ẹ béèrè lọ́wọ́ Olúwa fún mi àti fún àwọn ènìyàn àti fún gbogbo Júdà nípa ohun tí a kọ sínú ìwé yìí tí a ti rí. Gíga ni ìbínú Olúwa tí ó ń jó sí wa nítorí àwọn baba wa kò tẹ̀lé ọ̀rọ̀ inú ìwé yìí; wọn kò ṣe ní ìbámu pẹ̀lú gbogbo ohun tí a kọ níbẹ̀ nípa wa.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 22

Wo 2 Ọba 22:13 ni o tọ