Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 21:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi kò ní jẹ́ kí ẹsẹ̀ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì yẹ̀ kúrò láti ilẹ̀ tí èmi fi fún àwọn babańlá wọn tí ó bá jẹ́ wí pé wọn yóò ṣe àkíyèsí láti ṣe gbogbo ohun tí èmi ti paláṣẹ fún wọn kí wọn sì pa gbogbo òfin tí ìránṣẹ́ mi Móṣè fi fún wọn mọ́.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 21

Wo 2 Ọba 21:8 ni o tọ