Ṣùgbọ́n àwọn ènìyàn náà kò tẹ́tí. Mánásè tàn wọ́n ṣíwájú, bẹ́ẹ̀ ni kí wọ́n lè ṣe búburú ju gbogbo orílẹ̀ èdè tí Olúwa tí parun níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì lọ.