Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 21:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì gbé fínfín ère òrìṣà tí ó ti ṣe ó sì gbé e sínú ilé Olúwa, èyí tí Olúwa ti sọ fún Dáfídì àti sí ọmọ rẹ̀ Ṣólómónì, “Nínú ilé Olúwa yìí àti ní Jérúsálẹ́mù, tí èmi ti yàn jáde lára gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì, èmi yóò kọ orúkọ mi títí láéláé.

Ka pipe ipin 2 Ọba 21

Wo 2 Ọba 21:7 ni o tọ