Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 21:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò sì kọ ìyókù àwọn ìní mi sílẹ̀ èmi yóò sì kó wọn lé àwọn ọ̀ta wọn lọ́wọ́. Wọn yóò sì di ìkógun àti ìjẹ fún gbogbo àwọn ọ̀ta wọn,

Ka pipe ipin 2 Ọba 21

Wo 2 Ọba 21:14 ni o tọ