Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 21:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí pé wọ́n ti ṣe búburú ní ojú mi, wọ́n sì ti mú mi bínú láti ọjọ́ tí babańlá wọn ti jáde wá láti Éjíbítì títí di òní yìí.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 21

Wo 2 Ọba 21:15 ni o tọ