Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 18:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èyí ṣẹlẹ̀ nítorí wọn kò pa àṣẹ Olúwa Ọlọ́run wọn mọ́. Ṣùgbọ́n wọ́n ti dà májẹ̀mú rẹ̀ gbogbo èyí tí Móṣè ìránṣẹ́ Olúwa ti pa láṣẹ. Wọn kò fi etí wọn sílẹ̀ sí òfin wọn kò sì gbé wọn jáde.

Ka pipe ipin 2 Ọba 18

Wo 2 Ọba 18:12 ni o tọ