Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 16:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba Ásíríà sì gbọ́ tirẹ̀: nítórí ọba Ásíríà gòkè wá sí Dámásíkù, ó sì kó o, ó sì mú un ní ìgbékùn lọ sí Kírì, ó sì pa Résínì.

Ka pipe ipin 2 Ọba 16

Wo 2 Ọba 16:9 ni o tọ