Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 16:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì lọ sí Dámásíkù láti pàdé Tigilati-Pílésérì, ọba Ásíríà, ó sì rí pẹpẹ kan tí ó wà ní Dámásíkù: Áhásì ọba sì rán àwòrán pẹpẹ náà, àti àpẹẹrẹ rẹ̀ sí Úráyà àlùfáà, gẹ́gẹ́ bí gbogbo iṣẹ́ ọ̀nà rẹ̀.

Ka pipe ipin 2 Ọba 16

Wo 2 Ọba 16:10 ni o tọ