Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 16:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhásì sì mú fàdákà àti wúrà tí a rí ní ilé Olúwa, àti nínú ìṣúrà ilé ọba, ó sì rán an sí ọba Ásíríà ní ọrẹ.

Ka pipe ipin 2 Ọba 16

Wo 2 Ọba 16:8 ni o tọ