Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Ọba 16:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhásì sì rán oníṣẹ́ sọ́dọ̀ Tigilati-Pílésérì ọba Ásíríà wí pé, “Ìránṣẹ́ rẹ ni èmi, àti ọmọ rẹ; gòkè wá, kí o sì gbà mi lọ́wọ́ ọba Síríà, àti lọ́wọ́ ọba Ísírẹ́lì tí ó díde sí mi.”

Ka pipe ipin 2 Ọba 16

Wo 2 Ọba 16:7 ni o tọ