Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 6:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó wí pé:“Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì, kò sí Ọlọ́run tí ó dà bí rẹ ní ọ̀run àti ní ayé: ìwọ tí o pa májẹ̀mú ìfẹ́ rẹ mọ́ pẹ̀lú àwọn ìránṣẹ́ rẹ tí ń fi tọkàntọkàn wọn rìn ní ọ̀nà rẹ.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 6

Wo 2 Kíróníkà 6:14 ni o tọ