Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 6:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì ṣe àga idẹ kan tí ó jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ márùn ún ní gígùn àti ìgbọ̀nwọ́ márùn ún fífẹ̀ àti ìgbọ̀nwọ́ mẹ́ta ní gíga, a gbé e sí àárin àgbàlá ti òde. Ó sì dúró ní orí rẹ̀, àti pé ó kúnlẹ̀ lórí eékún rẹ̀ níwájú gbogbo ìjọ ènìyàn Isírẹ́lì, ó sì tẹ́ ọwọ́ọ rẹ̀ méjèèjì sí òkè ọ̀run.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 6

Wo 2 Kíróníkà 6:13 ni o tọ