Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 32:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó kọ́ àwọn ilé pẹ̀lú láti tọ́jú àwọn ọkà àwọn tí wọ́n ka, ọtí titun àti òróró; ó sì ṣe àwọn àtíbàbà fún oríṣìí àwọn ẹran ọ̀sìn àti àwọn àsémọ́ fun àwọn ọ̀wọ̀ ẹran.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 32

Wo 2 Kíróníkà 32:28 ni o tọ