Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 32:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nísinsinyìí, ẹ má ṣe jẹ́ kí Heṣekáyà ó tàn yín àti sì yín tọ́ sọ́nà báyìí. Ẹ má se gbàá gbọ́, nítorí tí kò sí Ọlọ́run orílẹ̀-èdè mìíràn tàbí ìjọba tí ó ní agbára láti gba àwọn ènìyàn rẹ̀ kúrò lọ́wọ́ mi tàbí lọ́wọ́ àwọn bàbá mi, mélòómélòó wa ni Ọlọ́run yín tí yóò gbà yín kúrò lọ́wọ́ mi!”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 32

Wo 2 Kíróníkà 32:15 ni o tọ