Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 32:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni nínú gbogbo àwọn òrìṣà orílẹ̀ èdè wọ̀nyí tí àwọn baba mi ti parun, tí ó le gbà ènìyàn rẹ̀ lọ́wọ́ mi, tí Ọlọ́run yín yóò fi le gbà yín lọ́wọ́ mi?

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 32

Wo 2 Kíróníkà 32:14 ni o tọ