Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 31:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba dá láti ara ohun ìni rẹ̀ fun ọrẹ sísun àárọ̀ àti ìrọ̀lẹ́ àti fún ọrẹ sísun ní ọjọ́ ìsinmi, òṣùpá tuntun àti àsè yíyàn gẹ́gẹ́ bi a ti se kọ ọ́ nínú òfin Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 31

Wo 2 Kíróníkà 31:3 ni o tọ