Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 31:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Heṣekíà fi lé àwọn àlùfáà àti àwọn ará Léfì lọ́wọ́ sí àwọn ìpín olúkúlùkù wọn gẹ́gẹ́ bí isẹ́ wọn gẹ́gẹ́ bí àlùfáà tàbí ará Léfì láti tẹ́ ọrẹ sísun àti ọrẹ ìdàpọ̀, láti ṣe iṣẹ́ ìránṣẹ́ láti fi ọpẹ́ fún àti láti kọ àwọn orin ìyìn ní ẹnu ọ̀nà ibùgbé Olúwa.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 31

Wo 2 Kíróníkà 31:2 ni o tọ