Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 31:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kórè ọmọ ímínà ará Léfì Olùtọ́jú ẹnu ọ̀nà ìlà oòrùn, wà ní ìkáwọ́ àwọn ọrẹ àtinúwá tí a fi fún Ọlọ́run, pí pín ìdáwó tí a ṣe fún Olúwa pẹ̀lú àwọn ẹ̀bùn tí a yà sọ́tọ̀

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 31

Wo 2 Kíróníkà 31:14 ni o tọ