Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 31:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jéhíélì, Áṣáṣíà, Náhátì, Ásáhélì, Jérímótì, Joábádì, Élíélì, Ísímákíà, Máhátì àti Bénáyà jẹ́ àwọn alábojútó lábẹ́ Konáníà àti Ṣíméhì arákùnrin rẹ̀ nípa ipá ọba Heṣekáyà àti Áṣáríyà oníṣẹ́ ti ó wà ní ìkáwọ́ ilé Ọlọ́run.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 31

Wo 2 Kíróníkà 31:13 ni o tọ