Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 25:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó kó gbogbo wúrà àti fàdákà àti gbogbo ohun èlò tí wọ́n rí ni ile Ọlọ́run tí ọ́ wà ní àbojútó Obedi Édómù, lápapọ̀ pẹ̀lú àwọn ìṣura ààfin àti àwọn ìdógó, ó sì padà sí Saaríà.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 25

Wo 2 Kíróníkà 25:24 ni o tọ