Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 25:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jóásì ọba Ísírẹ́lì fi agbára mú Áhásáyà ọba Júdà, ọmọ Jóáṣì ọmọ Áhásáyà ní Bétì Ṣéméṣì. Nígbà náà Jóásì mú u wá sí Jérúsálẹ́mù. Ó sì wó ògiri Jérúsálẹ́mù lulẹ̀ láti ẹnu ọ̀nà Éfíráímù sí igun ẹnu ọ̀nà apá kan títí ń lọ sí ọgọ́rùnún mẹ́fà ẹsẹ̀ bàtà ní gígùn.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 25

Wo 2 Kíróníkà 25:23 ni o tọ