Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 25:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìbínú Olúwa ru sí Ámásíà, ó sì rán wòlíì kan sí i, tí ó wí pé, “kí ni ó dé tí ìwọ fi ń bèrè lọ́wọ́ àwọn Ọlọ́run àwọn ènìyàn yìí, tí wọn kò le gba àwọn ènìyàn ti wọn kúrò lọ́wọ́ rẹ?”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 25

Wo 2 Kíróníkà 25:15 ni o tọ