Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 25:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó ti n sọ̀rọ̀, ọba wí fún un pé, “Ṣé a yàn ọ́ ní olùgbà ọba lámọ̀ràn ni? Dúró! Èéṣe tí a ó fi lù ọ́ bolẹ̀?”Bẹ́ẹ̀ ni, wòlíì náà dúró ṣùgbọ́n ó wí pé, “Èmi mọ̀ pé Olúwa ti pinnu láti pa ọ́ run nítorí ìwọ ti ṣe èyí, ìwọ kò sì tẹ́tísí ìmọ̀ràn mi”

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 25

Wo 2 Kíróníkà 25:16 ni o tọ