Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 1:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sólómónì ọmọ Dáfídì fìdí ara rẹ̀ múlẹ̀ ṣinṣin lórí ìjọba rẹ̀. Nítorí tí Olúwa Ọlọ́run rẹ̀ wà pẹ̀lú u rẹ̀, ó sì jẹ́ kí ó ga lọ́pọ̀lọpọ̀.

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 1

Wo 2 Kíróníkà 1:1 ni o tọ