Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

2 Kíróníkà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà, Sólómónì bá gbogbo Ísírẹ́lì sọ̀rọ̀ sí àwọn alákóso ẹgbẹgbẹ̀rún àti àwọn alákòóso ọ̀rọ̀rún, sí àwọn adájọ́ àti sí gbogbo àwọn olórí Ísírẹ́lì, àwọn olórí ìdílé

Ka pipe ipin 2 Kíróníkà 1

Wo 2 Kíróníkà 1:2 ni o tọ