Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 20:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jónátanì sì wí fún Dáfídì pé, “Má a lọ ní àlàáfíà, bí o ti jẹ́ pé àwa méjèèjì tí júmọ búra ni orukọ Olúwa pé, ‘Ki Olúwa ó wà láàrin èmi àti ìwọ, láàrin irú-ọmọ mi àti láàrin irú-ọmọ rẹ̀ láéláé.’ ” Òun sì dìde, ó sì lọ kúrò: Jónátanì sì lọ sí ìlú.

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 20

Wo 1 Sámúẹ́lì 20:42 ni o tọ