Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Sámúẹ́lì 20:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Níwọ̀n ìgbà tí ọmọ Jésè bá wà láàyè lórí ilẹ̀ ayé, a kì yóò fi ẹṣẹ̀ ìwọ tàbí ti ìjọba rẹ múlẹ̀. Nísinsìn yìí ránṣẹ́ kí o sì lọ mú un wá fún mi, nítorí ó gbọ́dọ̀ kú!”

Ka pipe ipin 1 Sámúẹ́lì 20

Wo 1 Sámúẹ́lì 20:31 ni o tọ