Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 22:43 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì rìn nínú gbogbo ọ̀nà Áṣà baba rẹ̀, kò sì yípadà kúrò nínú rẹ̀; ó sì ṣe èyí tí ó tọ́ ní ojú Olúwa. Kìkì àwọn ibi gíga ni a kò mú kúrò, àwọn ènìyàn sì ń rú ẹbọ, wọ́n sì ń sun tùràrí níbẹ̀.

Ka pipe ipin 1 Ọba 22

Wo 1 Ọba 22:43 ni o tọ