Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 22:42 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jèhósáfátì sì jẹ́ ẹni ọdún márùndínlógójì nígbà tí ó bẹ̀rẹ̀ sí ń jọba ní ọdún mẹ́ẹ̀dọ́gbọ̀n ní Jérúsálẹ́mù. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Ásúbà ọmọbìnrin Sílíhì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 22

Wo 1 Ọba 22:42 ni o tọ