Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 22:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Míkáyà sì dáhùn pé, “Mo rí gbogbo Ísírẹ́lì túkáàkiri lórí àwọn òkè bí àgùntàn tí kò ní olùṣọ́, Olúwa sì wí pé, ‘Àwọn wọ̀nyí kò ní olúwa. Jẹ́ kí olúkúlùkù padà sí ilé rẹ̀ ní àlàáfíà.’ ”

Ka pipe ipin 1 Ọba 22

Wo 1 Ọba 22:17 ni o tọ