Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 22:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọba sì wí fún un pé, “Ìgbà mélòó ni èmi yóò fi ọ bú pé kí o má ṣe sọ ohun kan fún mi bí kò ṣe òtítọ́ ní orúkọ Olúwa?”

Ka pipe ipin 1 Ọba 22

Wo 1 Ọba 22:16 ni o tọ