Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 21:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Èmi yóò mú ibi wá sórí rẹ. Èmi yóò sì mú ìran rẹ kúrò, èmi yóò sì ké kúrò lọ́dọ̀ Áhábù gbogbo ọmọdé ọkùnrin, àti ọmọ ọ̀dọ̀, àti òmìnira ní Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin 1 Ọba 21

Wo 1 Ọba 21:21 ni o tọ