Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 21:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Áhábù sì wí fún Èlíjà pé, “Ìwọ ti rí mi, ìwọ ọ̀ta mi!”Ó sì dáhùn wí pé, “Èmi ti rí ọ, nítorí tí ìwọ ti tan ara rẹ láti ṣe búburú níwájú Olúwa.

Ka pipe ipin 1 Ọba 21

Wo 1 Ọba 21:20 ni o tọ