Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 21:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò ṣe ilé rẹ bí ilé Jéróbóámù, ọmọ Nébátì, àti bí ilé Bááṣà, ọmọ Áhíjà, nítorí ìwọ ti mú mi bínú, ìwọ sì ti mú Ísírẹ́lì ṣẹ̀.’

Ka pipe ipin 1 Ọba 21

Wo 1 Ọba 21:22 ni o tọ