Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 21:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ fún un pé, ‘Báyìí ni Olúwa wí: Ǹjẹ́ ìwọ kò ti pa ènìyàn, o sì ti fi agbára gba ogún rẹ̀?’ Nígbà náà ni kí o wí fún un pé, ‘Báyìí ni Olúwa wí: Níbi tí ajá gbé lá ẹ̀jẹ̀ Nábótì, ni àwọn ajá yóò lá ẹ̀jẹ̀ rẹ, àní tìrẹ!’ ”

Ka pipe ipin 1 Ọba 21

Wo 1 Ọba 21:19 ni o tọ