Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí Olúwa kí ó lè pa ìlérí rẹ̀ tí ó sọ nípa tèmi mọ́ pé: ‘Bí àwọn ọmọ rẹ bá kíyèsí ọ̀nà wọn, tí wọ́n bá sì fi gbogbo àyà wọn àti ọkàn wọn rìn níwájú mi ní òtítọ́, o kì yóò sì kùnà láti ní ọkùnrin kan lórí ìtẹ́ Ísírẹ́lì.’

Ka pipe ipin 1 Ọba 2

Wo 1 Ọba 2:4 ni o tọ