Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

kí o sì wòye ohun tí Olúwa Ọlọ́run rẹ béèrè, rìn ní ọ̀nà rẹ̀, kí o sì pa àṣẹ àti òfin rẹ̀ mọ́, àti ìdájọ́ rẹ, àti ẹ̀rí rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí a ti kọ ọ́ nínú ìwé òfin Mósè, nítorí kí ìwọ kí ó le è máa ṣe rere ní ohun gbogbo tí ìwọ ṣe, àti ní ibikíbi tí ìwọ bá lọ,

Ka pipe ipin 1 Ọba 2

Wo 1 Ọba 2:3 ni o tọ