Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 19:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èlíṣà sì fi í sílẹ̀, ó padà ṣẹ́yìn. Ó sì mú àjàgà màlúù rẹ, ó sì pa wọ́n. Ó sì fi ohun-èlò àwọn màlúù náà bọ́ ẹran wọn, ó sì fi fún àwọn ènìyàn, wọ́n sì jẹ. Nígbà náà ni ó sì dìde láti tọ Èlíjà lẹ́yìn, ó sì ṣe ìránṣẹ́ fún un.

Ka pipe ipin 1 Ọba 19

Wo 1 Ọba 19:21 ni o tọ