Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 19:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni Èlíṣà sì fi àwọn màlúù sílẹ̀, ó sì ṣáré tọ Èlíjà lẹ́yìn. Ó wí pé, “Èmi bẹ̀ ọ́, jẹ́ kí èmi lọ fi ẹnu ko baba àti ìyá mi ní ẹnu. Nígbà náà ni èmi yóò tọ̀ ọ́ lẹ́yìn.”Èlíjà sì dáhùn wí pé, “Padà ṣẹ́yìn, kí ni mo fi ṣe ọ́?”

Ka pipe ipin 1 Ọba 19

Wo 1 Ọba 19:20 ni o tọ