Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 19:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni Èlíjà lọ kúrò níbẹ̀, ó sì rí Èlíṣà ọmọ Sáfátì. Ó ń fi àjàgà màlúù méjìlá tulẹ̀ níwájú rẹ̀, àti òun náà níwájú ìkéjìlá. Èlíjà sì tọ̀ ọ́ lọ, ó sì da agbádá rẹ̀ bò ó.

Ka pipe ipin 1 Ọba 19

Wo 1 Ọba 19:19 ni o tọ