Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

1 Ọba 17:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Obìnrin náà sì wí fún Èlíjà pé, “Nísinsìnyìí mo mọ̀ pé ènìyàn Ọlọ́run ni ìwọ ń ṣe, àti pé òtítọ́ ni ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ní ẹnu rẹ.”

Ka pipe ipin 1 Ọba 17

Wo 1 Ọba 17:24 ni o tọ